Yorùbá Bibeli

Luk 2:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si kiyesi i, ọkunrin kan wà ni Jerusalemu, orukọ rẹ̀ a ma jẹ Simeoni; ọkunrin na si ṣe olõtọ ati olufọkànsin, o nreti itunu Israeli: Ẹmí Mimọ́ si bà le e.

Luk 2

Luk 2:18-27