Yorùbá Bibeli

Luk 19:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

O nwipe, Ibaṣepe iwọ mọ̀, loni yi, ani iwọ, ohun ti iṣe ti alafia rẹ! ṣugbọn nisisiyi nwọn pamọ́ kuro li oju rẹ.

Luk 19

Luk 19:41-48