Yorùbá Bibeli

Luk 18:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Jesu si gbọ́ eyi, o wi fun u pe, Ohun kan li o kù fun ọ sibẹ: lọ ità ohun gbogbo ti o ni, ki o si pín i fun awọn talakà, iwọ o si ni iṣura li ọrun: si wá, ki o mã tọ̀ mi lẹhin.

Luk 18

Luk 18:20-30