Yorùbá Bibeli

Luk 17:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si da a lohùn, nwọn bi i pe, Nibo, Oluwa? O si wi fun wọn pe, Nibiti okú ba gbé wà, nibẹ̀ pẹlu ni idì ikojọ pọ̀ si.

Luk 17

Luk 17:29-37