Yorùbá Bibeli

Luk 17:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ na, eniti o ba wà lori ile, ti ẹrù rẹ̀ si mbẹ ni ile, ki o máṣe sọkalẹ lati wá kó o; ẹniti o ba si wà li oko, ki o máṣe pada sẹhin.

Luk 17

Luk 17:28-35