Yorùbá Bibeli

Luk 17:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn njẹ, nwọn nmu, nwọn ngbeyawo, nwọn si nfà iyawo fun ni, titi o fi di ọjọ ti Noa wọ̀ inu ọkọ̀ lọ, kíkun omi si de, o si run gbogbo wọn.

Luk 17

Luk 17:18-36