Yorùbá Bibeli

Luk 17:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn Farisi bi i pe, nigbawo ni ijọba Ọlọrun yio de, o da wọn li ohùn pe, Ijọba Ọlọrun ki iwá pẹlu àmi:

Luk 17

Luk 17:17-25