Yorùbá Bibeli

Luk 16:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pẹlu gbogbo eyi, a gbe ọgbun nla kan si agbedemeji awa ati ẹnyin, ki awọn ti nfẹ má ba le rekọja lati ìhin lọ sọdọ nyin, ki ẹnikẹni má si le ti ọ̀hun rekọja tọ̀ wa wá.

Luk 16

Luk 16:24-29