Yorùbá Bibeli

Luk 15:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo wi fun nyin, gẹgẹ bẹ̃li ayọ̀ yio wà li ọrun lori ẹlẹṣẹ kan ti o ronupiwada, jù lori olõtọ mọkandilọgọrun lọ, ti kò ṣe aini ironupiwada.

Luk 15

Luk 15:4-8