Yorùbá Bibeli

Luk 15:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn baba na wi fun awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀ pe, Ẹ mu ãyo aṣọ wá kánkán, ki ẹ si fi wọ̀ ọ; ẹ si fi oruka bọ̀ ọ lọwọ, ati bàta si ẹsẹ rẹ̀:

Luk 15

Luk 15:18-29