Yorùbá Bibeli

Luk 14:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnikan ba tọ̀ mi wá, ti ko si korira baba rẹ̀, ati iya, ati aya, ati ọmọ, ati arakunrin, ati arabinrin, ani ati ẹmí ara rẹ̀ pẹlu, kò le ṣe ọmọ-ẹhin mi.

Luk 14

Luk 14:17-35