Yorùbá Bibeli

Luk 14:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ọkan ninu awọn ti o ba a joko tì onjẹ gbọ́ nkan wọnyi, o wi fun u pe, Ibukun ni fun ẹniti yio jẹun ni ijọba Ọlọrun.

Luk 14

Luk 14:6-16