Yorùbá Bibeli

Luk 13:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹkún ati ipahinkeke yio wà nibẹ̀, nigbati ẹnyin o ri Abrahamu, ati Isaaki, ati Jakọbu, ati gbogbo awọn woli, ni ijọba Ọlọrun, ti a o si tì ẹnyin sode.

Luk 13

Luk 13:26-35