Yorùbá Bibeli

Luk 13:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

O dabi wóro irugbin mustardi, ti ọkunrin kan mú, ti o si sọ sinu ọgbà rẹ̀; ti o si hù, o si di igi nla; awọn ẹiyẹ oju ọrun si ngbé ori ẹká rẹ̀.

Luk 13

Luk 13:10-29