Yorùbá Bibeli

Luk 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si kiyesi i, obinrin kan wà nibẹ̀ ti o ni ẹmí ailera, lati ọdún mejidilogun wá, ẹniti o tẹ̀ tan, ti ko le gbé ara rẹ̀ soke bi o ti wù ki o ṣe.

Luk 13

Luk 13:7-19