Yorùbá Bibeli

Luk 10:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni ile kanna ni ki ẹnyin ki o si gbé, ki ẹ mã jẹ, ki ẹ si mã mu ohunkohun ti nwọn ba fifun nyin; nitori ọ̀ya alagbaṣe tọ́ si i. Ẹ maṣe ṣi lati ile de ile.

Luk 10

Luk 10:6-16