Yorùbá Bibeli

Luk 10:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si dahùn wipe, Ki iwọ ki o fi gbogbo àiya rẹ, ati gbogbo ọkàn rẹ, ati gbogbo agbara rẹ, ati gbogbo inu rẹ fẹ Oluwa Ọlọrun rẹ; ati ẹnikeji rẹ bi ara rẹ.

Luk 10

Luk 10:20-28