Yorùbá Bibeli

Luk 10:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LẸHIN nkan wọnyi, Oluwa si yàn adọrin ọmọ-ẹhin miran pẹlu, o si rán wọn ni mejimeji lọ ṣaju rẹ̀, si gbogbo ilu ati ibi ti on tikararẹ̀ yio gbé de.

Luk 10

Luk 10:1-5