Yorùbá Bibeli

Luk 1:44-46 Yorùbá Bibeli (YCE)

44. Sawò o, bi ohùn kikí rẹ ti bọ́ si mi li etí, ọlẹ̀ sọ ninu mi fun ayọ̀.

45. Alabukun-fun si li ẹniti o gbagbọ́: nitori nkan wọnyi ti a ti sọ fun u lati ọdọ Oluwa wá yio ṣẹ.

46. Maria si dahùn, o ni, Ọkàn mi yìn Oluwa logo,