Yorùbá Bibeli

Luk 1:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Elisabeti gbọ́ kikí Maria, ọlẹ̀ sọ ninu rẹ̀; Elisabeti si kún fun Ẹmí Mimọ́:

Luk 1

Luk 1:35-43