Yorùbá Bibeli

Luk 1:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori on o pọ̀ niwaju Oluwa, kì yio si mu ọti-waini, bẹ̃ni kì yio si mu ọti-lile; yio si kún fun Ẹmi Mimọ́ ani lati inu iya rẹ̀ wá.

Luk 1

Luk 1:7-23