Yorùbá Bibeli

Luk 1:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn angẹli na wi fun u pe, Má bẹ̀ru, Sakariah: nitoriti adura rẹ gbà; Elisabeti aya rẹ yio si bí ọmọkunrin kan fun ọ, iwọ o si sọ orukọ rẹ̀ ni Johanu.

Luk 1

Luk 1:3-19