Yorùbá Bibeli

Lef 8:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mú ọrá na, ati ìru ti o lọrá, ati gbogbo ọrá ti o mbẹ lara ifun, ati àwọn ti o bò ẹ̀dọ, ati iwe mejeji, ati ọrá wọn, ati itan ọtún:

Lef 8

Lef 8:22-31