Yorùbá Bibeli

Lef 25:55 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe iranṣẹ mi li awọn ọmọ Israeli iṣe; iranṣẹ mi ni nwọn ti mo mú lati ilẹ Egipti jade wá: Emi li OLUWA Ọlọrun nyin.

Lef 25

Lef 25:51-55