Yorùbá Bibeli

Lef 24:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mú ẹniti o ṣe ifibu nì wá sẹhin ibudó; ki gbogbo awọn ti o si gbọ́ ọ ki o fi ọwọ́ wọn lé ori rẹ̀, ki gbogbo ijọ enia ki o le sọ ọ li okuta.

Lef 24

Lef 24:8-22