Yorùbá Bibeli

Lef 20:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ọkàn ti o ba yipada tọ̀ awọn ti o ní ìmọ afọṣẹ, ati ajẹ́, lati ṣe àgbere tọ̀ wọn lẹhin, ani emi o kọju mi si ọkàn na, emi o si ke e kuro lãrin awọn enia rẹ̀.

Lef 20

Lef 20:1-10