Yorùbá Bibeli

Lef 20:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnyin ki o si jẹ́ mimọ́ fun mi: nitoripe mimọ́ li Emi OLUWA, mo si ti yà nyin sọ̀tọ kuro ninu awọn orilẹ-ède, ki ẹnyin ki o le jẹ́ ti emi.

Lef 20

Lef 20:22-27