Yorùbá Bibeli

Lef 20:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li ẹnyin o ṣe ma pa gbogbo ìlana mi mọ́, ati gbogbo idajọ mi, ki ẹnyin si ma ṣe wọn: ki ilẹ na, ninu eyiti mo mú nyin wá tẹ̀dó si, ki o má ṣe bì nyin jade.

Lef 20

Lef 20:15-24