Yorùbá Bibeli

Lef 2:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa ki o si sun ẹbọ-iranti rẹ̀, apakan ninu ọkà gigún rẹ̀, ati apakan ninu oróro rẹ̀, pẹlu gbogbo turari rẹ̀: ẹbọ ti a fi iná ṣe ni si OLUWA.

Lef 2

Lef 2:13-16