Yorùbá Bibeli

Lef 2:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyiti o si kù ninu ẹbọ ohunjijẹ, ki o jẹ́ ti Aaroni, ati ti awọn ọmọ rẹ̀: ohun mimọ́ julọ ni, ọrẹ-ẹbọ OLUWA ti a fi iná ṣe.

Lef 2

Lef 2:5-16