Yorùbá Bibeli

Lef 14:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si fi wọ́n ẹniti a o wẹ̀numọ́ kuro ninu ẹ̀tẹ nigba meje, ki o si pè e ni mimọ́, ki o si jọwọ ẹiyẹ alãye nì lọwọ lọ si gbangba oko.

Lef 14

Lef 14:1-14