Yorùbá Bibeli

Lef 14:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki nwọn ki o si mú okuta miran, ki nwọn ki o si fi i di ipò okuta wọnni, ki nwọn ki o si mú ọrọ miran ki nwọn ki o si fi rẹ́ ile na.

Lef 14

Lef 14:39-46