Yorùbá Bibeli

Lef 14:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki alufa ki o paṣẹ ki nwọn ki o yọ okuta na kuro lara eyiti àrun na gbé wà, ki nwọn ki o si kó wọn lọ si ibi aimọ́ kan lẹhin ilu na:

Lef 14

Lef 14:39-50