Yorùbá Bibeli

Lef 11:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi ni ki ẹnyin ki o ma jẹ ninu gbogbo ohun ti mbẹ ninu omi: ohunkohun ti o ba ní lẹbẹ ati ipẹ́, ninu omi, ninu okun, ati ninu odò, awọn ni ki ẹnyin ki o ma jẹ.

Lef 11

Lef 11:1-19