Yorùbá Bibeli

Lef 10:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Mose wi fun Aaroni pe, Eyiyi li OLUWA wipe, A o yà mi simimọ́ ninu awọn ti nsunmọ mi, ati niwaju awọn enia gbogbo li a o yìn mi li ogo. Aaroni si dakẹ.

Lef 10

Lef 10:1-12