Yorùbá Bibeli

Jud 1:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Mikaeli, olori awọn angẹli, nigbati o mba Èṣu jà, ti o nṣì jijakadi nitori okú Mose, kò si gbọdọ sọ ọ̀rọ-odi si i, ṣugbọn o wipe, Oluwa ni yio ba ọ wi.

Jud 1

Jud 1:1-10