Yorùbá Bibeli

Jud 1:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egbé ni fun wọn! nitoriti nwọn ti rìn li ọ̀na Kaini, nwọn si fi iwọra súré sinu ìṣina Balaamu nitori ère, nwọn si ṣegbé ninu iṣọtẹ̀ Kora.

Jud 1

Jud 1:10-21