Yorùbá Bibeli

Jon 1:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn ọkunrin na bẹ̀ru gidigidi, nwọn si wi fun u pe, Ẽṣe ti iwọ fi ṣe eyi? nitori awọn ọkunrin na mọ̀ pe o sá kuro niwaju Oluwa, nitori on ti sọ fun wọn.

Jon 1

Jon 1:9-16