Yorùbá Bibeli

Joh 9:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun u pe, Lọ, wẹ̀ ninu adagun Siloamu, (itumọ̀ eyi ti ijẹ Ránlọ.) Nitorina o gbà ọ̀na rẹ̀ lọ, o wẹ̀, o si de, o nriran.

Joh 9

Joh 9:4-11