Yorùbá Bibeli

Joh 9:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu si wipe, Nitori idajọ ni mo ṣe wá si aiye yi, ki awọn ti kò riran, le riran; ati ki awọn ti o riran le di afọju.

Joh 9

Joh 9:33-41