Yorùbá Bibeli

Joh 9:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina nwọn si tun wi fun afọju na pe, Kini iwọ wi nitori rẹ̀, nitoriti o là ọ loju? O si wipe, Woli ni iṣe.

Joh 9

Joh 9:11-18