Yorùbá Bibeli

Joh 9:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn Farisi pẹlu tún bi i lẽre, bi o ti ṣe riran. O si wi fun wọn pe, O fi amọ̀ le oju mi, mo si wẹ̀ mo si riran.

Joh 9

Joh 9:10-24