Yorùbá Bibeli

Joh 9:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O dahùn o si wi fun wọn pe, ọkunrin kan ti a npè ni Jesu li o ṣe amọ̀, o si fi kùn mi loju, o si wi fun mi pe, Lọ si adagun Siloamu, ki o si wẹ̀: emi si lọ, mo wẹ̀, mo si riran.

Joh 9

Joh 9:2-16