Yorùbá Bibeli

Joh 8:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyini nwọn wi, nwọn ndán a wò, ki nwọn ba le ri ohun lati fi i sùn. Ṣugbọn Jesu bẹrẹ silẹ, o si nfi ika rẹ̀ kọwe ni ilẹ.

Joh 8

Joh 8:1-15