Yorùbá Bibeli

Joh 8:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu wi fun wọn pe, Ibaṣepe Ọlọrun ni Baba nyin, ẹnyin iba fẹran mi: nitoriti emi ti ọdọ Ọlọrun jade, mo si wá: bẹ̃li emi kò si wá fun ara mi, ṣugbọn on li o rán mi.

Joh 8

Joh 8:34-48