Yorùbá Bibeli

Joh 8:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo ni ohun pupọ̀ lati sọ, ati lati ṣe idajọ nipa nyin: ṣugbọn olõtọ li ẹniti o ran mi, ohun ti emi si ti gbọ lati ọdọ rẹ̀ wá, nwọnyi li emi nsọ fun araiye.

Joh 8

Joh 8:19-35