Yorùbá Bibeli

Joh 8:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O wipe, Kò si ẹnikan, Oluwa. Jesu si wi fun u pe, Bẹ̃li emi na kò da ọ lẹbi: mã lọ, lati igbayi lọ má dẹṣẹ̀ mọ́.

Joh 8

Joh 8:4-12