Yorùbá Bibeli

Joh 6:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

A sá ti kọ ọ ninu iwe awọn woli pe, A o si kọ́ gbogbo wọn lati ọdọ Ọlọrun wá. Nitorina ẹnikẹni ti o ba ti gbọ́, ti a si ti ọdọ Baba kọ́, on li o ntọ̀ mi wá.

Joh 6

Joh 6:44-52