Yorùbá Bibeli

Joh 6:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu wi fun wọn pe, Emi li onjẹ ìye: ẹnikẹni ti o ba tọ̀ mi wá, ebi kì yio pa a; ẹniti o ba si gbà mi gbọ́, orungbẹ kì yio gbẹ ẹ mọ́ lai.

Joh 6

Joh 6:33-41