Yorùbá Bibeli

Joh 6:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jesu wi fun wọn pe, Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun nyin, kì iṣe Mose li o fi onjẹ nì fun nyin lati ọrun wá; ṣugbọn Baba mi li o fi onjẹ otitọ nì fun nyin lati ọrun wá.

Joh 6

Joh 6:26-42